Video Gbese Remix Feat Qdot de Niniola 2024 Dance Lyrics

Escucha la música Dance más popular de Niniola y otros artistas en línea. Disfruta de las mejores canciones de 2024 en Musicas-Cristianas de música en línea. ¡Encuentra tu canción favorita y escúchala en cualquier momento y en cualquier lugar!

Video Gbese Remix Feat Qdot » Niniola Letra

INICIONiniolaGbese Remix Feat Qdot

Niniola - Gbese Remix Feat Qdot Lyrics


Ẹ ra motor 150 thousand, ẹnì k'oma taku lóru
Ẹ tí jonz (ẹ jonz)
Ẹ ti jonz (ẹ jonz)

Nini dé
(Ẹ jonz)
Ẹ gb'ọtí lẹ, kẹ jonz
Ẹnu o ẹnu, ọrọ ẹnu important
Ẹnu lẹ'nu temi, máfi bèrè òun tó dára
K'oma gbàgbé mí, Ẹlẹ'dàá mí
Irè pàdé mí

Jẹlosimi, lọ jókò (ẹ lọ jókò)
Ẹ kéré gan, ẹ tí pọ tó (ẹ tí pọ tó)
Bàbá Ìjẹ'bú fún mí l'eyọ kan
Fún mí ní number kín jẹ, kín tà tete eh

Àre tí bèrè, kẹ suure síbí
Ẹ t'ara ṣáṣá ké gbé soolu, kìí body yìn tele
Mójú kelele, b'òṣùpá bà yọ k'aṣeré alẹ (kúrò ńbẹ)
You really wanna turn the party down
Party don turn on a boggy-boogy down, go down, well done
I like the way you do
When there's life, there is hope
Believe in yourself, don't belittle yourself
(Wolo, wolo-wolo wolo-wolo)

(Gbésẹ́) gbésẹ́ sókè o (gbésẹ́)
Gbé body sókè o (gbésẹ́)
Ọmọ ológo gbéra tan (gbésẹ́)
Jí, másún (gbésẹ́)
Ẹnì ṣáṣẹ l'agbowó (gbésẹ́)
Ọlọhun o s'ọjoró (gbésẹ́)
Nkuyo, owo mi dá o? (Gbesẹ́)
Ẹ máa jẹ ko japa o (gbésẹ́)
Gbésẹ́ sókè oh (gbésẹ́)
Gbé body sókè o (gbésẹ́)

(Kúrò ńbẹ) goat dey dance, aboki dey laugh
Goat no know say aboki wan use am for suya
Òyìnbó ní, " Life is vocabulary, methaphorlosis
Life is concogariculous, " ọrọ lẹṣín òwe

T'ẹmi bawa, ìrètí ń bẹ
Kola Olawuyi ní Nkan Ńbẹ
Nítorí ọbọ o j'ọgẹdẹ mọ, owo l'ejo ńjẹ
Gbogbo slay mama, come and miliki to my music
It's very unique, nourish bí ti miliki

Kiki, do you love me?
Are you riding? Do you really want me?
T'Olubadan báwọ knicker burger, bọọlu ló fẹ lọ gbà (gbà-gbá-gbà)
T'oba rí NEPA to ń lo laptop, boya wire lo fín ja

(Gbésẹ́) gbesẹ sókè o (gbésẹ́)
Gbé body sókè o (gbésẹ́)
Ọmọ ológo gbéra tan (gbésẹ́)
Jí, másún (gbésẹ́)
Ẹnì ṣáṣẹ l'agbowó (gbésẹ́)
Ọlọrun o s'ọjoró (gbésẹ́)

Nkuyo, owo mi dá o? (Gbésẹ́)
Ẹ máa jẹ ko japa o (gbésẹ́)
Àwọn ọmọ benefit (gbésẹ́)
Cotonou wọ Port Novo (gbésẹ́)
Gbé body sókè o
Àwọn slay mama tóń bà tí rí Snapchat
Wọn a tọ'jú, t'ete
Wọn a demo' pẹlú flower lórí

Jẹlosimi, lọ jókò (ẹ lọ jókò)
Ẹ kéré gan ẹ tí pọ tó (ẹ tí pọ tó)
Bàbá Ìjẹ'bú fún mí l'eyọ kan
Fún mí ní number kín jẹ, kín tà tete eh

(Gbésẹ́) gbésẹ́ sókè oh (gbésẹ́)
Gbé body sókè oh (gbésẹ́)
Xsmile, bámí lu'lu (gbésẹ́)
Wọn tún tí jẹmi lówó (gbésẹ́)
IBD Dende (gbésẹ́)
Mo mọ Sir Kuti (gbésẹ́)
Mo mọ Femi Jaguar (gbésẹ́)
Lanre Typical (gbésẹ́)

Òrìṣà ní Baddy Ooṣha oh (gbésẹ́)
Arowolo ló ń ta motor oh (gbésẹ́)
Òun ta motor ni Texas (gbésẹ́)
K Sir, Sosse (gbésẹ́)
King of Marley (gbésẹ́)
Ọba Bombay (gbésẹ́)
Àkúré Oloyemẹkun (gbésẹ́)
Mo mọ Hot Water oh (gbésẹ́)
Èèyàn Iko Modina (gbésẹ́)

Aremọ Gucci (gbésẹ́)
Kẹhinde Fatai mi (gbésẹ́)
Tata, Emeka (gbésẹ́)
Niyass King Chievo (gbésẹ́)
Aláṣẹ Nikas, Teni level ní (gbésẹ́)
Ọmọ ọba Kumasi (gbésẹ́)

Lekan Agbainaki (gbẹsẹ)
Mo mọ Billique (gbésẹ́)
Mo mọ Milli Hustle (gbésẹ́)
Otunba Cash (gbésẹ́)
Abu Abel (gbésẹ́)
Wọn à ni aji wọn lorin kọ (gbésẹ́)
Ìyẹn láṣe tún kọ (gbésẹ́)
Uh-uh, uh-uh-nh
Yeah, who's here?

Gbese Remix Feat Qdot » Niniola Letras !!!
Esta sitio web no aloja ningún tipo de archivo audio o video© Musicas-Cristianas 2024 España | Chile - Argentina - México. Todos los derechos reservados.

Escuchar músicas enlinea gratis, 2024 Escuchar Música Online, Música en Línea 2024, Música en Línea Gratis, Escuchar Música Gratis, Música Online 2024, Escuchar Música

Música 2024, Música 2024 Online, Escuchar Música Gratis 2024, Músicas 2024 Gratis, Escuchas top, Música de Moda.