Video Owo Wa de Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band 2024 Lyrics Lyrics

Escucha la música Lyrics más popular de Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band y otros artistas en línea. Disfruta de las mejores canciones de 2024 en Musicas-Cristianas de música en línea. ¡Encuentra tu canción favorita y escúchala en cualquier momento y en cualquier lugar!

Video Owo Wa » Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band Letra

INICIOBeautiful Nubia And The Roots Renaissance BandOwo Wa

Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band - Owo Wa Lyrics


O mi be'ju ironu wo mi, eyi koja owe o (owe o, owe o, owe o eh)
Seb'eni a wi fun k'oba je o gbo, iyen l'abo alakori
L'ai te'ti s'ogbon ipile, a o ti'ka ete ba'nu po l'ojo kan o (ye o, yeh o, eh)
O pe mo ti nba o so, ijo wo lo ma gbo awe o?

T'a ba fe k'o dara fun wa, k'ojo ola ye wa o
Sebi l'owo wa lo wa, owo wa l'o wa eni're
Ni'jo a ti nba'ra pade ni mo ti nsi o ni'ye yi o
Abi owo wa l'o wa, owo wa l'o wa eni're
O f'aake ko'ri ko'ti ikun oju mi nfa roro o
Sebi owo wa l'o wa, owo wa l'o wa eni're
T'a ba fe k'o dara fun wa, ki'le aye wa ko dun k'ale
Owo wa l'o wa, owo wa l'o wa

Oju orun ma su dede ara gbola ajanilaya
(Ye o, ye o, ye o, ye)
T'a ba le yi'wa pada ona atunse a la gerere
A o t'omo s'ona iye, eemo o se ni wo'le wa ba ni l'osan gangan (Ye o, ye o, eh)
O wa nwo mi pakopako, emi lo a fe ntun ma wi?

T'a ba fe k'o dara fun wa, k'ojo ola ye wa o
Sebi l'owo wa lo wa, owo wa l'o wa eni're
Ni'jo a ti nba'ra pade ni mo ti nsi o ni'ye yi o
Abi owo wa l'o wa, owo wa l'o wa eni're
O f'aake ko'ri ko'ti ikun oju mi nfa roro o
Sebi owo wa l'o wa, owo wa l'o wa eni're
T'a ba fe k'o dara fun wa, ki'le aye wa ko dun k'ale
Owo wa l'o wa, owo wa l'o wa

T'a ba fe k'o dara fun wa, k'ojo ola ye wa o
Sebi l'owo wa lo wa, owo wa l'o wa eni're
Ni'jo a ti nba'ra pade ni mo ti nsi o ni'ye yi o
Abi owo wa l'o wa, owo wa l'o wa eni're
O f'aake ko'ri ko'ti ikun oju mi nfa roro o
Sebi owo wa l'o wa, owo wa l'o wa eni're
T'a ba fe k'o dara fun wa, ki'le aye wa ko dun k'ale
Owo wa l'o wa, owo wa l'o wa

Owo wa, owo wa, owo wa lo wa

Owo wa, owo wa, owo wa lo wa

Owo wa, owo wa, owo wa lo wa

Owo wa, owo wa, owo wa lo wa

Owo wa, owo wa, owo wa lo wa

Owo Wa » Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band Letras !!!
Esta sitio web no aloja ningún tipo de archivo audio o video© Musicas-Cristianas 2024 España | Chile - Argentina - México. Todos los derechos reservados.

Escuchar músicas enlinea gratis, 2024 Escuchar Música Online, Música en Línea 2024, Música en Línea Gratis, Escuchar Música Gratis, Música Online 2024, Escuchar Música

Música 2024, Música 2024 Online, Escuchar Música Gratis 2024, Músicas 2024 Gratis, Escuchas top, Música de Moda.